Music: ISE IYANU - OKIKIAYANJESU ft. Oreoluwani PraiseNigerian Singer and Songwriter IKUFISILE OPEOLUWA popularly known as OKIKIAYANJESU drop another power song tagged "ISE IYANU" featuring Oreoluwani Praise.

OKIKIAYANJESU is a gifted singer, songwriter, Percussionist and an educationist.

He started his musical career way back since 1999 in lagos ,where he sang in his family church, FIRST BAPTIST CHURCH ABULE-EGBA ,He has been around the altar, which brought about his  first album in 2005, He sings Gospel Highlife, High Praise, and Gospel JUJU.

His songs are very inspiring, He sings the mind of God to the world and he is highly anointed, He strongly believes that everyone is created for a purpose which needs to be discovered, he has 3 new tracks to her First album titled" MODUPE ORE, AFOBAJE and now ISE IYANU.

He is currently based in Lagos, Nigeria currently worships at FBC ABULE-EGBA.LYRICS

(Talking Drum Pronounce )

Kosohun to'lorun olese
Boba Sojo
Asoda, aseekan bii otutu
Aseekan, amu bii oye
Ko sohun to'lorun olese

(Instrumental)

Chorus: Yio sele, Iyanu maa sele laye mi (2ce) Call&Res

Solo 1: Emi Yio gboju mi sori oke wonni oo
Nibo niranlowo mi Yio wa tii wa
Iranlowo mii Yio towo olodumare oba wa, Oba to da orun ohun aye oo
Ohun Kii Yio je ki Ese mi ki o ye nigbakan kan(rara rarara)
Oti soro ase jade.... Lodun yiii ooo
Wipe......

Chorus(Yio sele iyanu maa sele laye mi, Yio sele iyanu maa sele laye mi)

(Instrumental)

Solo 2: Bibeli lofi ye mi, pe Omo kinihun ama salaini, ebi asii maa pa won ni bibeli mi so
Sugbon awon to ba tii ni oo....kii oo jogun ofoo, gbede lon ro Koko lagbala....
Ninu odun yii
Iyanu maa sele ni mo Soo...

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mii, Yio sele iyanu maa sele laye mi)

(Instrumental)

Solo(OREOLUWA)
In the history of the bible lati rise iyanu,
Iyanu akoko nipe..
Oro manna fawon Omo isrelii oo, oopese mimu ninu igbeyawo,
Igbeyawo ni canna aati galili ooo yen
Iwo to so omi dii wine

Olana setii okun
Iru ise iyanu woo looti see, mi o tii ri, baba rere baba ke, 
Iwo lonise iyanu, otidamiloju oma siise iyanu ooooo eeee,
Oyaa gbogbo eti to gbo mii maa bere fun ise iyanu..
Gbogbo enu to le so, oyaa maa soro ise iyanu torii Yio sele, Yio sele, Yio sele lodun yiii.....

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mii.
Iyanu toju arii ooo, tetii de maa gbo nii....

Chorus: Yio sele, iyanu maa sele laye mi)
Gbogbo onise ijoba
Emaa rona gbegba ooo (Amin)

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mii)
Gbogbo onisowo patapata ee maa rere Oja jee o ooo

(Chorus: Yio sele Iyanu maa sele laye mi)
Gbogbo Omo Ile owe
Eee maa rerin ayooo, lodun yiii

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mi)
Gbogbo alaboyun patapata, emaa towo ala'bosun oooo(pelu iyanu)

Chorus: Yio sele iyanu maa,sele laye mii)
Oni' robinuje okan'
Odamiloju lo'dun yii waa rii tii ee se.

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mi)
Iwo taati ro pin pe oolebuyoo, lodun yii waa soro soke...

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mi)
Iyanu maa sele, teeti agbo, toju arii, tenu Yio so, lodun yiii oo ooooo

Chorus: Yio sele iyanu maa sele laye mi ooooo.

Post a Comment

Previous Post Next Post