Music: Felix Ajagunna - OLORUN GAGARA

Music: Felix Ajagunna - OLORUN GAGARA


Dynamic Gospel Juju musician, recording artist and a prolific song-writer; Felix Ajagunna also known as ABANISE1 releases another brand new single titled OLORUN GAGARA
 
ABOUT THE SONG
The song OLORUN GAGARA is an uplifting melody that give us the full certainty to degree that nothing can never replace incredible God in our lives on the grounds that is the Greatest God.

Listen, Download & Share
 

     DOWNLOAD NOW    

Also available on AUDIOMACK

 
LYRICS - OLORUN GAGARA
eso falagbara gagara
Pe mololorun gagara
eni koye se gagara
Lori aye mi mo 2ce
Ogun idile mama
Alagbara gagara ni
Kasise bi erin jeje eliri
Alagbara gagara ni
Airolore nile aye
Alagbara gagara ni
Airi bati se nile aye
Alagbara gagara ni
Ai rogo lo nile aye
Alagbara gagara ni
Eso falagbara gagara
Pe mololorun gagara
Eni koye se gagara
Lori aye mi mo

Chrs:
Unlee Olorun gagara
Olorun gagara
Oba toje mimo towo mimo
Olorun gagara
Totun fi mimo bora bi aso
Olorun gagara
Alagbara lori aye gbogbo sir
Olorun gagara
O ba ni mule mama dani
Olorun gagara
Kiniun eya judah
olorun gagara
O ran mo lajo wole deni
Olorun gagara

Goliath lojosi bo se ga gagara
Komo pe dafidi kekere
ololorun gagara
Kiise nipa giga laye
Tabi nipa agbara

Bikose ka lolorun gagara
Goliath wipe
Iwo omo kekere yiooo
Ofe bamija
maa pa e bi aja
Dafidi daalohun
O ni gbo goliath
Mo too wa  loruko olorun gagara
Ti iwo gan ti iwo mu kere
 
Okuta kan pere
Odi gbas erin subu
Erin wo erin subu
ewa wo aye alagbara ton se gagara
oti gbagbe wipe mo lolorun gagara
ewo aye alagbara ton se gagara
Eso falagbara gagara
pe mo lolorun gagara
Eni koye se gagara lori aye mi mo
 
Chrs:
Oba Nebukadnesari lojosi
To gberaga solorun
Ale kuro
Lori ite oba
O deranko o ba eranko je
Olorun fii han wipe
Ohun ni olorun gagara
Gbogba  eni tom se gagara
Lori aye mi oooo
Jowo je kan mo wipe mo lolorun gagara
Eso falagbara gagara
Pe mo lolorun gagara
Eni koye se gagara lori aye mi mo
 
Chrus:
Pariwo unle olorun gagara
Olorun gagara
Alagbara gigagiga
Olorun gagara
Baba omo emi mimo meta lokan
Olorun gagara
Olorun akinkemi mojiba  re
Olorun gagara
Olorun arakeji mojuba lodo re
Olorun gagara
Oba alagbara lori aye

Olorun gagara
Abani mule mama dani
Olorun gagara
Olorun abanise mojubre
Olorun gagara

Follow Felix Ajagunna on: facebook, instagram for new music and ministry updates.

Facebook: Felix ajagunna
Instagram: abanise1official
Contact: 08162070737

Post a Comment

0 Comments